Language/Yoruba/Grammar/Oro-asopo-(Conjunctions)
Jump to navigation
Jump to search
Rate this lesson:
Kini Oro Asopo ? (Conjunctions)
Oro asopo je awon oro ti a maa nlo lati so gbolohun kan tabi meji papo.Fun apeere: ati, oun ,sugbon,amo, afi/ayafi, abbl.
Conjunctions are words used to join two or more sentences together.For example: and,but, neither nor, either or, together with, except,etc.
Apeere bi a nse lo oro asopo ninu gbolohun:
Examples of how to use conjunctions in sentences:
- Olu ati Ade je ewa.
- Bimbo ko mo iwe ayafi ko sere.
- Ojo su amo ko to