Language/Yoruba/Grammar/Onka-Yoruba-(Counting-and-Numbers-in-Yoruba)

From Polyglot Club WIKI
< Language‎ | Yoruba‎ | Grammar
Jump to navigation Jump to search
This lesson can still be improved. EDIT IT NOW! & become VIP
Rate this lesson:
5.00
(one vote)

ONKA YORUBA (Counting of Numbers in Yoruba)
Yoruba-Language-PolyglotClub.png

Okan - Aadota

One - Fifty

Gbogbo eya ati ede ni won ni bi won ti se ma nka nkan ni ede.

Every race and nation has a way of counting in their own language).

Idi niyi ti onka se pataki julo ninu Isiro tabi eto oro aje.

That is why numbers are very important in Mathematics and Commerce/ Economics.

Loni a o ma gbeyewo bi a n se ma ka onka lati okan titi de aadota ni ede Yoruba:

Today we will be examining how to count from one to fifty in Yoruba Language:

1 - 20[edit | edit source]

  • 1: okan
  • 2: eeji
  • 3: eta
  • 4: erin
  • 5: aarun
  • 6: efa
  • 7: eje
  • 8: ejo
  • 9: esan
  • 10 : ewa
  • 11: okanla
  • 12: ejila
  • 13: etala
  • 14: erinla
  • 15: aarundinlogun/ meedogun
  • 16: erindinlogun
  • 17: etadinlogun
  • 18: ejidinlogun
  • 19: okandinlogun
  • 20: Ogun

21 - 24[edit | edit source]

Lati 21 - 24 a o ma sope mokanle....,mejile... abbl.

From 21- 24 we will be saying it in the order of increase 20+1, 20+2, etc.

  • 21: mokanlelogun.
  • 22: mejilelogun
  • 23: metalelogun
  • 24: merinlelogun

25 - 29[edit | edit source]

Lati 25 - 29 a o ma sope marundin...., merindin..., abbl

From 25 to 29, we will be saying it in the order of decrease 30-5 ,30-4, etc.

  • 25: marundinlogbon
  • 26: merindinlogbon
  • 27: metadinlogbon
  • 28: mejidinlogbon
  • 29: mokandinlogbon

30 - 50[edit | edit source]

  • 30: ogbon
  • 40: ogoji
  • 41: mokanlelogoji
  • 42: mejilogoji, abbl (etc)
  • 45: marundinlaadota
  • 46: merindinlaadota ,abbl( etc)
  • 50: Aadota.

Mo lero wipe e gbadun ise naa ? A o tun ma rira Lori ise miran lae pe. O dabo! 😀

I hope you enjoy the lesson. See you very soon in another lesson. Bye! 😀

Other Lessons[edit | edit source]

Contributors

Maintenance script and Vincent


Create a new Lesson