Language/Yoruba/Grammar/Onka-Yoruba-(Counting-and-Numbers-in-Yoruba)
ONKA YORUBA ( Counting of Numbers in Yoruba.)
Okan- Aadota(One- Fifty)
Gbogbo eya ati ede ni won ni bi won ti se ma nka nkan ni ede. (Every race and nation has a way of counting in their own language).
Idi niyi ti onka se pataki julo ninu Isiro tabi eto oro aje. (That is why numbers are very important in Mathematics and Commerce/ Economics).
Loni a o ma gbeyewo bi a n se ma ka onka lati okan titi de aadota ni ede Yoruba: (Today we will be examining how to count from one to fifty in Yoruba Language):
1 ____ okan
2 ____ eeji 3 ____ eta 4 ____ erin 5 ____ aarun 6 _____ efa 7 _____ eje 8 _____ ejo
9 _____ esan
10 _____ ewa 11 _____ okanla 12 _____ ejila 13 _____ etala 14 _____ erinla 15 _____ aarundinlogun/ meedogun 16 _____ erindinlogun 17 _____ etadinlogun 18 _____ ejidinlogun 19 _____ okandinlogun 20 _____ Ogun
Lati 21- 24 a o ma sope mokanle....,mejile... abbl.
From 21- 24 we will be saying it in the order of increase 20+1,20+2, etc.
21 _____ mokanlelogun. 22 _____ mejilelogun 23 _____ metalelogun 24 _____ merinlelogun
Lati 25 -29 a o ma sope marundin...., merindin...,abbl
From 25- 29 we will be saying it in the order of decrease 30-5 ,30-4, etc.
25 _____ marundinlogbon 26 _____ merindinlogbon 27 _____ metadinlogbon 28 _____ mejidinlogbon 29 _____ mokandinlogbon 30 _____ ogbon
40 _____ ogoji 41 _____ mokanlelogoji 42 _____ mejilogoji, abbl (etc)
45 _____ marundinlaadota 46 _____ merindinlaadota ,abbl( etc)
50 _____ Aadota.
Mo lero wipe e gbadun ise naa ?
A o tun ma rira Lori ise miran lae pe.
O dabo!
I hope you enjoy the lesson See you very soon in another lesson. Bye!