Language/Yoruba/Grammar/Oro-asopo-(Conjunctions)
Jump to navigation
Jump to search
Rate this lesson:
Kini Oro Asopo ?( Conjunctions)
Oro asopo je awon oro ti a maa nlo lati so gbolohun kan tabi meji papo.Fun apeere: ati, oun ,sugbon,amo, afi/ayafi, abbl.
Conjunctions are words used to join two or more sentences together.For example: and,but, neither nor, either or, together with, except,etc.
Apeere bi a nse lo oro asopo ninu gbolohun: 1.Olu ati Ade je ewa. 2.Bimbo ko mo iwe ayafi ko sere. 3.Ojo su amo ko to
Examples of how to use conjunctions in sentences: 1.Olu and Ade eat beans 2.Bimbo doesn't anything except to play 3.It is cloudy,but no rain.