Difference between revisions of "Language/Yoruba/Grammar/Onka-Yoruba-(Counting-and-Numbers-in-Yoruba)"
m (Quick edit) |
m (Quick edit) |
||
Line 5: | Line 5: | ||
__TOC__ | __TOC__ | ||
Gbogbo eya ati ede ni won ni bi won ti se ma nka nkan ni ede. | Gbogbo eya ati ede ni won ni bi won ti se ma nka nkan ni ede. | ||
<blockquote>Every race and nation has a way of counting in their own language).</blockquote> | <blockquote>Every race and nation has a way of counting in their own language).</blockquote> | ||
Idi niyi ti onka se pataki julo ninu Isiro tabi eto oro aje. | Idi niyi ti onka se pataki julo ninu Isiro tabi eto oro aje. | ||
<blockquote>That is why numbers are very important in Mathematics and Commerce/ Economics.</blockquote> | <blockquote>That is why numbers are very important in Mathematics and Commerce/ Economics.</blockquote> | ||
Loni a o ma gbeyewo bi a n se ma ka onka lati okan titi de aadota ni ede Yoruba: | Loni a o ma gbeyewo bi a n se ma ka onka lati okan titi de aadota ni ede Yoruba: | ||
Line 67: | Line 64: | ||
* 46: merindinlaadota ,abbl( etc) | * 46: merindinlaadota ,abbl( etc) | ||
* 50: Aadota. | * 50: Aadota. | ||
---- | ---- | ||
Line 73: | Line 69: | ||
<blockquote>I hope you enjoy the lesson. See you very soon in another lesson. Bye! 😀</blockquote> | <blockquote>I hope you enjoy the lesson. See you very soon in another lesson. Bye! 😀</blockquote> | ||
== | ==Other Lessons== | ||
* [[Language/Yoruba/Grammar/Gender|Gender]] | * [[Language/Yoruba/Grammar/Gender|Gender]] | ||
* [[Language/Yoruba/Grammar/Oro-asopo-(Conjunctions)|Oro asopo (Conjunctions)]] | * [[Language/Yoruba/Grammar/Oro-asopo-(Conjunctions)|Oro asopo (Conjunctions)]] | ||
Line 83: | Line 79: | ||
* [[Language/Yoruba/Grammar/Negation|Negation]] | * [[Language/Yoruba/Grammar/Negation|Negation]] | ||
* [[Language/Yoruba/Grammar/Pronouns|Pronouns]] | * [[Language/Yoruba/Grammar/Pronouns|Pronouns]] | ||
<span links></span> |
Latest revision as of 19:47, 27 March 2023
Okan - Aadota
One - Fifty
Gbogbo eya ati ede ni won ni bi won ti se ma nka nkan ni ede.
Every race and nation has a way of counting in their own language).
Idi niyi ti onka se pataki julo ninu Isiro tabi eto oro aje.
That is why numbers are very important in Mathematics and Commerce/ Economics.
Loni a o ma gbeyewo bi a n se ma ka onka lati okan titi de aadota ni ede Yoruba:
Today we will be examining how to count from one to fifty in Yoruba Language:
1 - 20[edit | edit source]
- 1: okan
- 2: eeji
- 3: eta
- 4: erin
- 5: aarun
- 6: efa
- 7: eje
- 8: ejo
- 9: esan
- 10 : ewa
- 11: okanla
- 12: ejila
- 13: etala
- 14: erinla
- 15: aarundinlogun/ meedogun
- 16: erindinlogun
- 17: etadinlogun
- 18: ejidinlogun
- 19: okandinlogun
- 20: Ogun
21 - 24[edit | edit source]
Lati 21 - 24 a o ma sope mokanle....,mejile... abbl.
From 21- 24 we will be saying it in the order of increase 20+1, 20+2, etc.
- 21: mokanlelogun.
- 22: mejilelogun
- 23: metalelogun
- 24: merinlelogun
25 - 29[edit | edit source]
Lati 25 - 29 a o ma sope marundin...., merindin..., abbl
From 25 to 29, we will be saying it in the order of decrease 30-5 ,30-4, etc.
- 25: marundinlogbon
- 26: merindinlogbon
- 27: metadinlogbon
- 28: mejidinlogbon
- 29: mokandinlogbon
30 - 50[edit | edit source]
- 30: ogbon
- 40: ogoji
- 41: mokanlelogoji
- 42: mejilogoji, abbl (etc)
- 45: marundinlaadota
- 46: merindinlaadota ,abbl( etc)
- 50: Aadota.
Mo lero wipe e gbadun ise naa ? A o tun ma rira Lori ise miran lae pe. O dabo! 😀
I hope you enjoy the lesson. See you very soon in another lesson. Bye! 😀
Other Lessons[edit | edit source]
- Gender
- Oro asopo (Conjunctions)
- Nouns
- Adjectives
- Questions
- Future Tense
- Conditional Mood
- Negation
- Pronouns