Difference between revisions of "Language/Yoruba/Grammar/Onka-Yoruba-(Counting-and-Numbers-in-Yoruba)"

From Polyglot Club WIKI
< Language‎ | Yoruba‎ | Grammar
Jump to navigation Jump to search
Line 42: Line 42:
==21 - 24==
==21 - 24==
Lati  21 - 24 a o ma sope mokanle....,mejile... abbl.
Lati  21 - 24 a o ma sope mokanle....,mejile... abbl.
<blockquote>From 21- 24 we will be saying it in the order of  increase  20+1,20+2, etc.</blockquote>
<blockquote>From 21- 24 we will be saying it in the order of  increase  20+1, 20+2, etc.</blockquote>


* 21: mokanlelogun.
* 21: mokanlelogun.
Line 48: Line 48:
* 23: metalelogun
* 23: metalelogun
* 24: merinlelogun
* 24: merinlelogun
==25 - 29==
==25 - 29==
Lati 25 - 29 a o ma sope marundin...., merindin..., abbl
Lati 25 - 29 a o ma sope marundin...., merindin..., abbl

Revision as of 14:25, 14 April 2022

ONKA YORUBA (Counting of Numbers in Yoruba)
Yoruba-Language-PolyglotClub.png

Okan - Aadota

One - Fifty


Gbogbo eya ati ede ni won ni bi won ti se ma nka nkan ni ede.

Every race and nation has a way of counting in their own language).


Idi niyi ti onka se pataki julo ninu Isiro tabi eto oro aje.

That is why numbers are very important in Mathematics and Commerce/ Economics.


Loni a o ma gbeyewo bi a n se ma ka onka lati okan titi de aadota ni ede Yoruba:

Today we will be examining how to count from one to fifty in Yoruba Language:

1 - 20

  • 1: okan
  • 2: eeji
  • 3: eta
  • 4: erin
  • 5: aarun
  • 6: efa
  • 7: eje
  • 8: ejo
  • 9: esan
  • 10 : ewa
  • 11: okanla
  • 12: ejila
  • 13: etala
  • 14: erinla
  • 15: aarundinlogun/ meedogun
  • 16: erindinlogun
  • 17: etadinlogun
  • 18: ejidinlogun
  • 19: okandinlogun
  • 20: Ogun

21 - 24

Lati 21 - 24 a o ma sope mokanle....,mejile... abbl.

From 21- 24 we will be saying it in the order of increase 20+1, 20+2, etc.

  • 21: mokanlelogun.
  • 22: mejilelogun
  • 23: metalelogun
  • 24: merinlelogun

25 - 29

Lati 25 - 29 a o ma sope marundin...., merindin..., abbl

From 25 to 29, we will be saying it in the order of decrease 30-5 ,30-4, etc.

  • 25: marundinlogbon
  • 26: merindinlogbon
  • 27: metadinlogbon
  • 28: mejidinlogbon
  • 29: mokandinlogbon

30 - 50

  • 30: ogbon
  • 40: ogoji
  • 41: mokanlelogoji
  • 42: mejilogoji, abbl (etc)
  • 45: marundinlaadota
  • 46: merindinlaadota ,abbl( etc)
  • 50: Aadota.

Mo lero wipe e gbadun ise naa ? A o tun ma rira Lori ise miran lae pe. O dabo! 😀

I hope you enjoy the lesson. See you very soon in another lesson. Bye! 😀