Difference between revisions of "Language/Yoruba/Grammar/Oro-asopo-(Conjunctions)"

From Polyglot Club WIKI
< Language‎ | Yoruba‎ | Grammar
Jump to navigation Jump to search
(No difference)

Revision as of 22:48, 8 April 2022

Kini Oro Asopo ? (Conjunctions)

Oro asopo je awon oro ti a maa nlo lati so gbolohun kan tabi meji papo.Fun apeere: ati, oun ,sugbon,amo, afi/ayafi, abbl.


Conjunctions are words used to join two or more sentences together.For example: and,but, neither nor, either or, together with, except,etc.


Apeere bi a nse lo oro asopo ninu gbolohun:

  1. Olu ati Ade je ewa.
  2. Bimbo ko mo iwe ayafi ko sere.
  3. Ojo su amo ko to


Examples of how to use conjunctions in sentences:

  1. Olu and Ade eat beans
  2. Bimbo doesn't anything except to play
  3. It is cloudy,but no rain.